Orin Dafidi 68:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ ni Ọlọrun ní ibi mímọ́ rẹ̀,Ọlọrun Israẹli;òun ni ó ń fún àwọn eniyan rẹ̀ ní ọlá ati agbára.Ìyìn ni fún Ọlọrun!

Orin Dafidi 68

Orin Dafidi 68:33-35