Orin Dafidi 68:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ń gun awọsanma lẹ́ṣin, àní awọsanma àtayébáyé;ẹ gbọ́ bí ó ṣe ń sán ààrá, ẹ gbọ́ ohùn alágbára.

Orin Dafidi 68

Orin Dafidi 68:26-35