Orin Dafidi 68:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“N óo kó wọn pada láti Baṣani,n óo kó wọn pada láti inú ibú omi òkun,

Orin Dafidi 68

Orin Dafidi 68:14-30