Orin Dafidi 68:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gun òkè gíga,ó kó àwọn eniyan nígbèkùn;ó gba ẹ̀bùn lọ́wọ́ àwọn eniyan,ati lọ́wọ́ àwọn ọlọ̀tẹ̀ pàápàá.OLUWA Ọlọrun yóo máa gbébẹ̀.

Orin Dafidi 68

Orin Dafidi 68:16-22