Orin Dafidi 66:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ òkun di ìyàngbẹ ilẹ̀,àwọn eniyan fi ẹsẹ̀ rìn kọjá láàrin odò.Inú wa dùn níbẹ̀ nítorí ohun tí ó ṣe.

Orin Dafidi 66

Orin Dafidi 66:5-15