Orin Dafidi 64:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù yóo sì ba gbogbo eniyan;wọn yóo máa sọ ohun tí Ọlọrun ti gbé ṣe,wọn yóo sì máa ronú nípa iṣẹ́ rẹ̀.

Orin Dafidi 64

Orin Dafidi 64:1-10