Orin Dafidi 62:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun nìkan ni mo fi sùúrù gbẹ́kẹ̀lé,nítorí ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi ti wá.

Orin Dafidi 62

Orin Dafidi 62:1-10