Orin Dafidi 62:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ti pẹ́ tó, tí gbogbo yín yóo dojú kọ ẹnìkan ṣoṣo, láti pa,ẹni tí kò lágbára ju ògiri tí ó ti fẹ́ wó lọ, tabi ọgbà tí ó fẹ́ ya?

Orin Dafidi 62

Orin Dafidi 62:1-11