Orin Dafidi 61:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ìwọ, Ọlọrun, ti gbọ́ ẹ̀jẹ́ tí mo jẹ́;o ti fún mi ní ogún tí o pèsè fún àwọn tí ó bẹ̀rù orúkọ rẹ.

Orin Dafidi 61

Orin Dafidi 61:1-8