Orin Dafidi 59:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó bí wọ́n ṣe lúgọ dè mí!OLUWA, àwọn jàǹdùkú eniyan kó ara wọn jọláti pa mí lára, láìṣẹ̀, láìrò.

Orin Dafidi 59

Orin Dafidi 59:1-11