Orin Dafidi 58:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan yóo wí nígbà náà pé,“Nítòótọ́, èrè ń bẹ fún olódodo;nítòótọ́, Ọlọrun ń bẹ tí ń ṣe ìdájọ́ ayé.”

Orin Dafidi 58

Orin Dafidi 58:5-11