Orin Dafidi 57:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, n óo máa fi ọpẹ́ fún ọ láàrin àwọn eniyan;n óo sì máa kọrin ìyìn sí ọ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè.

Orin Dafidi 57

Orin Dafidi 57:3-11