Orin Dafidi 57:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ranṣẹ láti ọ̀run wá, yóo gbà mí là,yóo dójú ti àwọn tí ń lépa ẹ̀mí mi.Ọlọrun yóo fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ati òtítọ́ rẹ̀ hàn!

Orin Dafidi 57

Orin Dafidi 57:1-5