Orin Dafidi 56:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó ara wọn jọ, wọ́n sápamọ́,wọ́n ń ṣọ́ ìrìn ẹsẹ̀ mi,bí wọn ṣé ń dọdẹ ẹ̀mí mi.

Orin Dafidi 56

Orin Dafidi 56:3-8