Orin Dafidi 55:22-23 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Kó gbogbo ìṣòro rẹ lé OLUWA lọ́wọ́,yóo sì gbé ọ ró;kò ní jẹ́ kí á ṣí olódodo ní ipò pada.

23. Ṣugbọn ìwọ, Ọlọrun, o óo sọ àwọn apaniati àwọn alárèékérekè, sinu kòtò ìparun;wọn kò ní lo ìdajì ọjọ́ ayé wọn.Ṣugbọn èmi óo gbẹ́kẹ̀lé ọ.

Orin Dafidi 55