Orin Dafidi 55:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ dùn ju oyin lọ,bẹ́ẹ̀ sì ni ìjà ni ó wà lọ́kàn rẹ̀;ọ̀rọ̀ rẹ̀ tutù ju omi àmù lọ,ṣugbọn idà aṣekúpani ni.

Orin Dafidi 55

Orin Dafidi 55:13-23