Orin Dafidi 55:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tí ó gúnwà láti ìgbàanì yóo gbọ́,yóo sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀,nítorí pé wọn kò pa ìwà wọn dà,wọn kò sì bẹ̀rù Ọlọrun.

Orin Dafidi 55

Orin Dafidi 55:14-23