Orin Dafidi 55:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń ráhùn tọ̀sán-tòru,mo sì ń kérora; OLUWA óo gbọ́ ohùn mi.

Orin Dafidi 55

Orin Dafidi 55:13-23