Orin Dafidi 55:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Tọ̀sán-tòru ni wọ́n ń yí orí odi rẹ̀ ká;ìwà ìkà ati ìyọnu ni ó sì pọ̀ ninu rẹ̀.

Orin Dafidi 55

Orin Dafidi 55:9-17