Orin Dafidi 53:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbá ti dára tó, kí ìgbàlà Israẹli ti Sioni wá!Nígbà tí Ọlọrun bá dá ire àwọn eniyan rẹ̀ pada,Jakọbu yóo yọ̀, inú Israẹli yóo sì dùn.

Orin Dafidi 53

Orin Dafidi 53:1-6