Orin Dafidi 52:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítòótọ́ Ọlọrun óo bá ọ kanlẹ̀,yóo gbá ọ mú, yóo sì fà ọ́ já kúrò ninu ilé rẹ;yóo fà ọ́ tu kúrò lórí ilẹ̀ alààyè.

Orin Dafidi 52

Orin Dafidi 52:1-9