Orin Dafidi 51:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹbọ tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ ìwọ Ọlọrun ni ẹ̀mí ìròbìnújẹ́,ọkàn ìròbìnújẹ́ ati ìrònúpìwàdà ni ìwọ kì yóo gàn.

Orin Dafidi 51

Orin Dafidi 51:8-19