Orin Dafidi 51:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni n óo máa kọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọ̀nà rẹ,àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ yóo sì máa yipada sí ọ.

Orin Dafidi 51

Orin Dafidi 51:9-19