Orin Dafidi 50:8 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ba yín wí nítorí ẹbọ rírú;nígbà gbogbo ni ẹ̀ ń rú ẹbọ sísun sí mi.

Orin Dafidi 50

Orin Dafidi 50:6-18