Orin Dafidi 50:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun wa ń bọ̀, kò dákẹ́:iná ajónirun ń jó níwájú rẹ̀;ìjì líle sì ń jà yí i ká.

Orin Dafidi 50

Orin Dafidi 50:1-12