Orin Dafidi 50:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun bi àwọn eniyan burúkú pé,“Ẹ̀tọ́ wo ni ẹ níláti máa ka àwọn òfin mi,tabi láti máa mú ẹnu ba ìlànà mi?

Orin Dafidi 50

Orin Dafidi 50:11-23