Orin Dafidi 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kò sí òtítọ́ kan lẹ́nu wọn;ìparun ni ó wà ninu ọkàn wọn.Isà òkú tí ó yanu sílẹ̀ ni ọ̀fun wọn;ẹnu wọn kún fún ìpọ́nni ẹ̀tàn.

Orin Dafidi 5

Orin Dafidi 5:1-11