Orin Dafidi 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nípa ọ̀pọ̀ ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀,èmi óo wọ inú ilé rẹ;n óo fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ wólẹ̀, n óo sì kọjúsí tẹmpili mímọ́ rẹ.

Orin Dafidi 5

Orin Dafidi 5:1-12