Orin Dafidi 49:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Dájúdájú, kò sí ẹni tí ó le ra ara rẹ̀ pada,tabi tí ó lè san owó ìràpadà ẹ̀mí rẹ̀ fún Ọlọrun;

Orin Dafidi 49

Orin Dafidi 49:4-17