Orin Dafidi 49:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé nígbà tí ó wà láàyè,ó rò pé Ọlọrun bukun òun,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ayé a máa yin eniyannígbà tí nǹkan bá ń dára fún un,

Orin Dafidi 49

Orin Dafidi 49:11-20