Orin Dafidi 49:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibojì wọn ni ilé wọn títí lae,ibẹ̀ ni ibùgbé wọn títí ayérayé,wọn ìbáà tilẹ̀ ní ilẹ̀ ti ara wọn.

Orin Dafidi 49

Orin Dafidi 49:9-18