Orin Dafidi 48:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkè mímọ́ rẹ̀, tí ó ga, tí ó sì lẹ́wà,ni ayọ̀ gbogbo ayé.Òkè Sioni, ní àríwá, lọ́nà jíjìn réré,ìlú ọba ńlá.

Orin Dafidi 48

Orin Dafidi 48:1-7