Orin Dafidi 47:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìjòyè orílẹ̀-èdè kó ara wọn jọpẹlu àwọn eniyan Ọlọrun Abrahamu.Ọlọrun ni aláṣẹ gbogbo ayé;òun ni ọlọ́lá jùlọ!

Orin Dafidi 47

Orin Dafidi 47:1-9