Orin Dafidi 46:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ dúró jẹ́ẹ́, kí ẹ sì mọ̀ pé èmi ni Ọlọrun.A gbé mi ga láàrin àwọn orílẹ̀-èdè,a gbé mi ga ní ayé.”

Orin Dafidi 46

Orin Dafidi 46:4-11