Orin Dafidi 45:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa gun ẹṣin ìṣẹ́gun lọ ninu ọlá ńlá rẹ,máa jà fún òtítọ́ ati ẹ̀tọ́,kí ọwọ́ ọ̀tún rẹ fún ọ ní ìṣẹ́gun ńlá.

Orin Dafidi 45

Orin Dafidi 45:1-6