Orin Dafidi 44:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa agbára rẹ ni a fi bi àwọn ọ̀tá wa sẹ́yìn,orúkọ rẹ ni a fi tẹ àwọn tí ó gbógun tì wá mọ́lẹ̀.

Orin Dafidi 44

Orin Dafidi 44:2-11