Orin Dafidi 44:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbéra nílẹ̀, kí o ràn wá lọ́wọ́!Gbà wá sílẹ̀ nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.

Orin Dafidi 44

Orin Dafidi 44:20-26