Orin Dafidi 44:13 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti sọ wá di ẹni ẹ̀gàn lọ́wọ́ àwọn aládùúgbò wa;a di ẹni ẹ̀sín ati ẹni yẹ̀yẹ́ lọ́dọ̀ àwọn tí ó yí wa ká.

Orin Dafidi 44

Orin Dafidi 44:9-14