Orin Dafidi 43:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Dá mi láre, Ọlọrun, kí o sì gbèjà mi,lọ́dọ̀ àwọn tí kò mọ̀ Ọ́;gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́tàn ati alaiṣootọ.

Orin Dafidi 43

Orin Dafidi 43:1-3