Orin Dafidi 42:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọ̀sán, OLUWA fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ hàn,ní òru, orin rẹ̀ gba ẹnu mi,àní, adura sí Ọlọrun ìyè mi.

Orin Dafidi 42

Orin Dafidi 42:5-10