Orin Dafidi 42:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọgbẹ́ aṣekúpanini ẹ̀gàn àwọn ọ̀tá mi rí lára mi,nígbà tí wọn ń bi mí lemọ́lemọ́ pé,“Níbo ni Ọlọrun rẹ wà?”

Orin Dafidi 42

Orin Dafidi 42:3-11