Orin Dafidi 40:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé àìmọye ìdààmú ló yí mi ká,ọwọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi ti tẹ̀ mí,tóbẹ́ẹ̀ tí n kò ríran.Wọ́n pọ̀ ju irun orí mi lọ,ọkàn mi ti dàrú.

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:6-17