Orin Dafidi 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dùbúlẹ̀, n óo sì sùn ní alaafia,nítorí ìwọ OLUWA nìkan ni o mú mi wà láìléwu.

Orin Dafidi 4

Orin Dafidi 4:3-8