Orin Dafidi 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Dá mi lóhùn nígbà tí mo bá pè ọ́,Ọlọrun mi olùdániláre.Ìwọ ni o yọ mí nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú,ṣàánú mi, kí o sì gbọ́ adura mi.

Orin Dafidi 4

Orin Dafidi 4:1-8