Orin Dafidi 38:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àárẹ̀ mú mi patapata, gbogbo ara sì wó mi;mò ń kérora nítorí ẹ̀dùn ọkàn mi.

Orin Dafidi 38

Orin Dafidi 38:1-14