Orin Dafidi 38:20-22 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Àwọn tí ń fi ibi san oore fún mi ní ń gbógun tì mí,nítorí pé rere ni mò ń ṣe.

21. OLUWA, má kọ̀ mí sílẹ̀,Ọlọrun mi, má jìnnà sí mi.

22. Yára wá ràn mí lọ́wọ́, OLUWA, ìgbàlà mi.

Orin Dafidi 38