Orin Dafidi 38:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí mi dẹ tàkúté sílẹ̀ dè mí,àwọn tí ń wá ìpalára mi ń sọ̀rọ̀ ìparun mi,wọ́n sì ń pète àrékérekè tọ̀sán-tòru.

Orin Dafidi 38

Orin Dafidi 38:11-13