Orin Dafidi 37:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, sì máa tọ ọ̀nà rẹ̀,yóo gbé ọ ga, kí o lè jogún ilẹ̀ náà;nígbà tí a bá pa àwọn eniyan burúkú run, o óo fojú rẹ rí i.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:28-40