Orin Dafidi 37:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí OLUWA fẹ́ràn ẹ̀tọ́;kò ní kọ àwọn olùfọkànsìn rẹ̀ sílẹ̀.Yóo máa ṣọ́ wọn títí lae,ṣugbọn a óo pa àwọn ọmọ eniyan burúkú run.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:25-29