Orin Dafidi 37:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan burúkú fa idà yọ, wọ́n sì kẹ́ ọfà wọnláti gba ẹ̀mí talaka ati aláìní,láti pa àwọn tí ń rìn lọ́nà ẹ̀tọ́.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:5-23